E ti tobi to by EmmaOMG featuring The OhEmGee Choir, PelumiDeborah, and OfficialBBO is a gospel track that emphasizes the greatness of God through its powerful lyrics and melodies.
The song’s recurring theme, “E ti tobi to o, Jesuuuuu” (“How great You are, Jesus”), underscores the central message of reverence and worship in the song.
Lines like “Gbogbo aye n wariri ni oruko re” (“The whole world trembles at Your name”) and “Awon orun n seleri, won foribale niwaju ite re” (“The heavens declare, they bow before Your throne”) highlight the awe and respect that believers are encouraged to feel.
Download the MP3 of “E ti tobi to (Live)” by EmmaOMG to engage with its meaningful lyrics, and visit our blog for additional gospel music downloads and related content.
Download the Audio, Stream, Share with friends and family, and stay blessed. Download MP3Download More EmmaOMG Songs Here
Song Lyrics: E Ti Tobi To Jesu by EmmaOMG
Oluwa tobi ni sioni
O si joba lori gbogbo orile ede
Je ki won yin oruko re ti o tobi ti osi leru
Oh my God……
Lead: Gbogbo aye n wariri ni oruko re
Won nkorin
Response: Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Lead: Awon orun n seleri won foribale niwaju ite re o, won so wipe
Response: Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Lead: Won ni Eti tobi to o
oh oh oh oluwa
Response: Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Lead: Won ni eti tobi to o,
oh oh oh oh oluwa wa o
Response: Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Lead: Awon oke nla nla won foribale o
Tori iwo ni ogo ati ola ju oke nla ikogun won ni lo o
Response: Eti tobi to o
Jesuuuuu
Lead: Iwo ti olorun ji dide ninu oku lati gba wa kuro ninu ibinu ti n bo o
Response: Eti tobi to o
Jesuuuuu
Lead: Iwo oluwa olorun to n gbe larin awon kerubu to po ni ipa ati agbara o
Response: Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Lead: Ani gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin ….yeee
Response: Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Lead: Awon orun n seleri won foribale niwaju ite re
Response: Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Lead: Eti tobi to o
oh oh oh oh oluwa wa o
Response: Eti tobi to o
Jesuuuuu
Lead: Ipekun ola, Ipekun iye ye eh eh eh eti tobi to oh oh oh oh
Response: Eti tobi oo
Jesuuuuu
Lead: Ireti wa o, eri wa o oh oh oh eti tobi to oh oh oh
Response: Eti tobi to ooo
Jesuuuuu
Lead: Itan sho to wole ro ro ro ro ro
Eti tobi to aye ati orun n bo oo
Response: (Won n juba) Eti tobi to o Jesuuu (won foribale)
Lead: Jordani ri o o pada seyin, okun ri o o sa
Eti tobi to olodumare
Response: Eti tobi to o
Jesuuuuu
Lead: Abetilukarabiajere baba mi agba oye
Eti tobi to oh oh oh oh oh
Response: Eti tobi oo
Jesuuuuu
Lead: Tori na gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin
Response: Eti tobi to o
Jesuuuuu
Lead: Awon orun n seleri won foribale niwaju ite re eh eh eh
Response: Eti tobi to o
Jesuuuuu
Lead: Won ni eti tobi to oo oh oh oh oluwa wa
Response: Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Lead: Gbogbo idile Jesse, jesu won nkorin foribale won so wipe
Response: Eti tobi to o
Jesuuuuu
Lead: Ipekun ola Ipekun Oro, Ipekun agbara oh eti tobi to
Eti tobi to oh oh oh oh oh
Response: Eti tobi to o
Jesuuuuu
Lead: Ore ati ola nla ni o wa ni iwaju re, ipa ati ewa nbe nibi mimo re
Response: Eti tobi to o
Jesuuuuu
Lead: Aiikakatan o, aiibubutan o atobi loye ongbe leyin eni a n da loro oo
Eti Eti Eti tobi to o
Response: Eti tobi to o
Jesuuuuu
Lead: Jesu gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin
Response: Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Lead: Awon orun n seleri won foribale niwaju ite re ohhhh eh
Response: Eti tobi to oo
Jesuuuuu
Lead: Won juba fun ajunilo o, eba n juba f’ajunilo eh, e ba n seba f’ajunilo o, e ba gbo’suba f’ajunilo, e ba n gbo osuba f’ajunilo o, e ba n kira f’ajunilo o, e ba n juba f’ajunilo o, e bami juba f’ajunilo, e ba n gbo’suba f’ajunilo o, e ba n seba f’ajunilo o
Ani gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin
Eti tobi to o Jesuuuuuuuuu
Oh My God